Documentary on History by Alaafin Oba Adeyemi III 
Interpreting the talking drums
World Sango Festival Documentary

Introduction


Welcome to Oyo Alaafin the Home of the Alaafin of OyoIkú dé ooooo,
Àrùn dé,
Òfò dé,
Àkóbá Ilé,
Àdábá òde,
Àdábá Ilé o
Àkóbá òde,
Ikú tíí pomo tí baba dúpé,
Àrùn tíí somo tí Ìyá ò gbodò gbin,
Àtàndá mó pa mí mo lémi ò yájú sóba,
Baàmi Àtàndá Oba Làmídì tí ñ jé Láyíwolá,
Àtàndá koko bí Owú,
Agbára bí Ota,
Bí ó wodò ariwo Esin,
Bí ó fodò ariwo Esin,
Kò réni bájà a wògiri kòrò-kòrò, 
Àgbàrá Òjò tíí báni jà tíí gbòde baba eni lówó eni,
Siyanbólá yo mí,
Oládìgbòlù yo mí,
Adéyemí yo mí,
Olówó gbogboro tíí yomo rè lófìn ,
Baàmi Àtàndá Oba Làmídì tí n jé Láyíwolá,
Omo àbàjà ò wopò eni ire níí ko ó,
Alábàjà jé á relé,
Òyó dùn joyin lo,
Dùndún laláàfin Òyó n jó,


Àtàndá dákun mó wo n mó, 
Ojú re ò sé woni,
Ìkan n somi,Ìkan n sèjè,
Ògbágbá wolè ó kàtiyo,
Eegun sónsó tíí parí Iké,


Omo omo Abiódún,
Tó bímo méta, méta òhún sì joba,
Àtìbà Oba,
Ládìgbòlù Oba,
Adéyemí Àtàndá ló sìketa,
Baàmi Àtàndá tó joba tí gbogbo Òyó n dùn yùngbà…
We invite the entire world to Oyo Alaafin for this year’s World Sango Festival taking place in Oyo Alaafin from 10th -19th of August 2023. Be There.
Alaafin Oba Adeyemi III on Oranyan
Conversation with the Alaafin